in

Oluwalonibisi – Oluwa Awa Omo Re De

Oluwalonibisi – Oluwa Awa Omo Re De – Yoruba Classic Hymn Volume 2

Oluwa Awa Omo Re De” is a stirring old yoruba hymn performed by Nigerian artist Oluwalonibisi. Taken from CCC Hymn 431, Oluwa Awa Omo Re De is a prophetic hymn that assures us that God still answers prayer. It was released as part of the “Yoruba Hymn Classic Volume Two” collection. Oluwalonibisi, known for his inspiring music, has a rich discography including songs like “Yoruba Hymns” and “Revival Hymns”.

Oluwa Awa Omo Re De Lyrics:

1. Oluwa, awa omo re de,

Lati gbohun ebe wa soke

Gegebi o ti gbo adura Elijah,

Jowo gbo adura wa.

2. O gbadura kojo mase ro,

Fun odun meta, on osu mefa

Gegebi o ti gbo adura Elijah,

Jowo gbo adura wa.

3. O si tun gbadura lekeji,

Ojo ro, ile si meso wa,

Gegebi o ti gbo adura Elijah,

Jowo gbo adura wa.

4. Adura lo n silekun anu,

Adura lo si Anna ninu,

Gegebi o ti gbo adura Elijah,

Jowo gbo adura wa. Amin

Listen, stream & download below:

Download Oluwalonibisi – Oluwa Awa Omo Re DeOluwalonibisi.mp3(Size: 4 MB)

Oluwalonibisi Oluwa Awa Omo Re De mp3 download.


Gbenga Akinfenwa – Revival Rain – Gbenga Akinfenwa – All Hail the King Live

Gbenga Akinfenwa – Revival Rain

Naledi Aphiwe – Ngiyabonga – Naledi Aphiwe Ngiyabonga Soundwela

Naledi Aphiwe – Ngiyabonga